Logo

    56. "Ibi tí a fi iyò sí ló nsomi sí."

    en-usFebruary 18, 2023
    What was the main topic of the podcast episode?
    Summarise the key points discussed in the episode?
    Were there any notable quotes or insights from the speakers?
    Which popular books were mentioned in this episode?
    Were there any points particularly controversial or thought-provoking discussed in the episode?
    Were any current events or trending topics addressed in the episode?

    About this Episode

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • ìwà ní njo oníwà lójú. 
    • ìwòn eku nìwòn ite; olongo kì í gbé tìmùtìmù. 
    • ìwòsí ní nba ilé àgbà jé. 
    • ìyàwó tó na omo obàkan, òrò ló fé gbó. 
    • Ibi tí a fi iyò sí ló nsomi sí.

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the show

    Recent Episodes from The Yoruba Proverbs Podcast with Bidemi Ologunde

    60. "Kí ni ó ya àpón lórí tó fisu síná tó nsúfèé pé “bí a ti nse ni inú mbí won?”"

    60. "Kí ni ó ya àpón lórí tó fisu síná tó nsúfèé pé “bí a ti nse ni inú mbí won?”"

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • Kí ni ìbá mú igúnugún dé òdò-o onídìrí? 
    • Kí ni ó ya àpón lórí tó fisu síná tó nsúfèé pé “bí a ti nse ni inú mbí won?” 
    • Kí ni onígbá nse tí aláwo ò lè se? 
    • Kí ni orí nse tí èjìká ò lè se? èjìká ru erù ó gba òódúnrún; orí ta tiè ní ogúnlúgba. 
    • Kí ni wón ti nse àmódù ní ìlorin? Ewúré njé béè.

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the show

    59. "Kíni ànfàní-i kètèkètè lára kétékété à-gùn-fesè-wólè?"

    59. "Kíni ànfàní-i kètèkètè lára kétékété à-gùn-fesè-wólè?"

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • Kékeré l’òpòló fi ga ju ilè lo. 
    • Kì í dowó-o baba kó ní ó di owó omo. 
    • Kíni ànfàní-i kètèkètè lára kétékété à-gùn-fesè-wólè? 
    • Kíni apárí nwá ní ìsò onígbàjámò? 
    • Kíni eléwé-e-gbégbé ntà tí ó nso pé ojà ò tà? 

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the show

    58. "Kàkà kí kìnìún se akápò ekùn, olóde a mú ode è se."

    58. "Kàkà kí kìnìún se akápò ekùn, olóde a mú ode è se."

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • Ká wí ogún, ká wí ogbòn, “Ng ò fé, ng ò gbà,” lasiwèré fi npèkun òràn. 
    • Kàkà kí àgbò ké, àgbò a kú. 
    • Kàkà kí bàbá ran omo ní àdá bo oko, oníkálukú a gbé tiè. 
    • Kàkà kí iga akàn ó padà sehìn, a kán. 
    • Kàkà kí kìnìún se akápò ekùn, olóde a mú ode è se. 

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the show

    57. "Ká ríni lóde ò dàbí-i ká báni délé."

    57. "Ká ríni lóde ò dàbí-i ká báni délé."

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • Jéjé leégún àgbà njó. 
    • Jòkùmò-ó se bí èlú, aró la bè lówè. 
    • Ká ríni lóde ò dàbí-i ká báni délé. 
    • Ká ríni sòrò fúnni ò dàbí-i ká sòrò fúnni ká gbà. 
    • Ká wí fúnni ká gbó; ká sòrò fúnni ká gbà; ká bèrè ònà lówó èrò tó kù léhìn káyé báa lè yeni. 

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the show

    56. "Ibi tí a fi iyò sí ló nsomi sí."

    56. "Ibi tí a fi iyò sí ló nsomi sí."

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • ìwà ní njo oníwà lójú. 
    • ìwòn eku nìwòn ite; olongo kì í gbé tìmùtìmù. 
    • ìwòsí ní nba ilé àgbà jé. 
    • ìyàwó tó na omo obàkan, òrò ló fé gbó. 
    • Ibi tí a fi iyò sí ló nsomi sí.

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the show

    55. "ìrùkèrè kì í yan ifá lódì; oge, dúró o kí mi."

    55. "ìrùkèrè kì í yan ifá lódì; oge, dúró o kí mi."

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • ìpénpéjú ò ní enini; àgbàlagbà irùngbòn ò se òlòó. 
    • Irú aso ò tán nínu àsà. 
    • ìrùkèrè kì í yan ifá lódì; oge, dúró o kí mi. 
    • ìsánsá ò yo ègún; ìsánsá kì í káwo obè. 
    • ìsé ò tibìkan múni; ìyà ò tibìkan je èèyàn; bí o bá rìnrìn òsì, bí o bá ojú ìsé wòlú, igbá-kúgbá ni won ó fi bu omi fún e mu. 

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the show

    54. "Ìpàkó onípàkó là nrí; enieléni ní nrí teni."

    54. "Ìpàkó onípàkó là nrí; enieléni ní nrí teni."

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • ìlu kan ò tó ègùn jo; bí a bá lù fún un a máa lu àyà. 
    • Iná njó ògiri ò sá; ó wá ngbá geere geere sómi. 
    • Inú burúkú làgbà nní, àgbà kì í ní ojú burúkú. 
    • Ipa ogbé ní nsàn; ipa ohùn kì í sàn. 
    • ìpàkó onípàkó là nrí; enieléni ní nrí teni. 

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the show

    53. "Ilé-ni-mo-wà kì í jèbi ejó."

    53. "Ilé-ni-mo-wà kì í jèbi ejó."

    In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:

    • ìjàlo ò lè gbé òkúta. 
    • ìjokòó eni ní múni da ewé èko nù. 
    • ìjoba npè ó, o ní ò nmu gààrí lówó; ta ní ni ó, ta ní ni omi tí o fi nmu gààrí? 
    • ilé-ni-mo-wà kì í jèbi ejó. 
    • ilé kì í jó kí baálé ilé tàkakà. Ilé kì í jó kí oorun kun ojú. 

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the show

    52. "Igúnnugún bà lé òrùlé; ojú tó ilé ó tó oko."

    Host Bidemi Ologunde analyzed five Yoruba proverbs describing self-respect, self-aggrandizement, and busybody behavior.

    1. Igúnnugún bà lé òrùlé; ojú tó ilé ó tó oko.
    2. Ìgbà tí sìgìdìí bá fé se eré èté, a ní kí wón gbé òun sójò.
    3. Ìgbà wo ni Mákùú ò níí kú? Mákùú ò mo awo ó mbú opa; Mákùú ò mo ìwè ó mbó sódò.
    4. Ihò wo lèkúté ngbé tó ní isé ilé ndíwó?
    5. Ìjàkùmò kì í rin lòsán, eni a bí ire kì í rin lòru.

    For questions, comments, or suggestions, please contact the host/producer, Bidemi Ologunde, by email bidemiologunde@gmail.com or on WhatsApp +1-702-983-0499.

    Support the show
    Logo

    © 2024 Podcastworld. All rights reserved

    Stay up to date

    For any inquiries, please email us at hello@podcastworld.io